Why Yoruba? ¬ Your Prof ¬ Syllabi ¬ Materials ¬ Student work ¬ Gallery ¬ Links

Ìwà Ìgbéraga
Mo rò pé ìwà ìgbéraga kò dára rárá. Orí«irí«i ìdí wà tí yóò kô æmædé pé ènìyàn tí ó jê onígbèrága kì í «e ènìyàn rere. Fún àp÷÷r÷, ènìyàn tí ó ní ìwà ìgbéraga rò nípa ara rë nìkan wôn sì «e nõkankínõkan fún ara wæn níkan. Nítorí náà, wôn kò ní öpölæpö örê inú ÷bí wæn kò sí dùn rárá pëlú ìwà ènìyàn onígbèrága.
by Hannah Levine (Fælákê)Mo mö ìtàn kan tí ó fi hàn ohun tí ó dé tí ìwà ìgbéraga kò dára.
Ní ìgbà láéláé, æmæbìnrin kan wà tí ó ñ gbé pëlú obí rë. ¿bí yìí kò ní owó rárá, «ùgbôn nígbà tí wôn ní owó díë, æmæbìnrin yìí fê kí obí rë fún un ní owó. Kò bìkítà bí ÷lòmíràn kò bá l'oúnj÷ tó. Æmæbìnrin yìí fê ní a«æ tuntun tàbí bàtà tuntun. Æmæbìnrin ní ìwà ìgbéraga. Síbësíbë, obí rë fêràn rë jù, wôn sì fún un ní ëbùn-- bí ó tí lë j÷ pé wón kò ní owó tó fún ara wæn. L'ójoojúmô ó di agbéraga ju.
Ní æjô kan, ebi pa ÷bí yìí gan an. Màmá rë bì í léèrè láti náwó fún búrêdi àti oògùn nìkan nítorí pé ara Bàbá rë kò yá rárá. Æmæbìinrin ké ó sì tún kígbe pé, "Kí l'ó dé tí mo gbódò læ rà nõkan wönyí fúnraara mi nígbà tí ÷ kò ní owó tó fún mi láti rà ëbùn fún ara mi?!"
Nígbà ti æmæbìnrin rà búrêdì kan, ó pinnu pé òun máa náwó fún bàtà tuntun kàkà kí òun rà oògùn. Ó fê wo bàtà tuntun gan an ni nítorí náà kò bìkítà pé Bàbá òun jê aláìsàn.
Nígbà tí ó rín sí ilé rë, ó dé ni ögædö tí ó ní ÷rë púpô. Kò lè yà sí æwô ötún, nítorí náà ó læ sí æwö òsì «ùgbôn ögædö yìí tóbi jù. Ó rí pé ó lè dá a kæjá bí ó bá fi búrêdi sorí ögædö yìí. Kò rò pé ebi pa ÷bí rë. Fún æmæbìnrin yìí, wiwö bàtà tuntun ni pàtàkì jùlæ.
Láì rò nípa ènìyàn mìíràn, ó bô búrêdi nínú ögædö kékeré ó sì rìn lórí búrêdi náà. Aah! Búrêdi náà bèrè sí mú! Láìpê bàtà rë tí ó fêràn gan an wà lábê ÷rë àti omi púpö. Æmæbìnrin kò lè kúrò ní ögædö! Ó rì!!
Nítorí èyí, æmæbìnrin yìí ní ìwà ìgbéraga-- ó rò nípa ara rë nìkan. Bí ó bá jê onírèlè, k'ìbá ti ní wàhálà yìí.
Why Yoruba? ¬
Your Prof ¬
Syllabi ¬
Materials ¬
Student work ¬
Gallery ¬
Links
UW-Madison home ¬
African Languages home ¬
Email
Copyright © 2000 The Board of Regents of the University
of Wisconsin System