Why Yoruba? ¬ Your Prof ¬ Syllabi ¬ Materials ¬ Student work ¬ Gallery ¬ Links

Blank title bar

Home

Agbégbö Pupa Kékeré
by Jermaine Jones (Olú«ínà)

Nígbá láéláé, Agbégbö kan wà tí ó ñ fê se búrëdì fún àwæn æmædé rë. ¿bí rë fêràn búrêdì gan an ni, «ùgbón kò rærùn rárá láti «e ètò fún búrêdì sise. Ní àkókó, ó ní láti læ sí æjà tí ó ní àlikàmà. Nígbà náà, ó «e dandan láti fi ælæ «e ìyëfun. Ní ikêyìn, Agbégbö gbôdö tinábò. Têlë, nígbà tí Agbégbö yìí ní ækæ, ó máa ñ «a àwæn fún ayá rë ó sì tinábò. Nísisìyí, Agbégbö opó mö pé i«ê yìí máa «òro nítorí pé àwæn æmædé wæn kéré- wôn kò lè ran màmá wæn lôwô.

Síbësíbë, Agbégbö yìí rò pé ó «e orí ire nítorí pé ó ní örê mêta dáadáa tí wôn máa ran ó lôwô láì «e àní àní. Nítorí náà, ó pinnu láti læ sí ibi Ajá ní àárö kùtùkùtù. Nígbà tí ó dé nibë, ó sæ pé, "¿ káàrö sa. Lónìí, mo fê se búrêdì fún æmædé mêrin mi, nítorí náà mo gbôdö rà àlikàmà lôdö æjà. Mo mö pé æjà ja jìnna láti ibi, «ùgbôn mo máa sanwó fún iranlôwô yin?" Ajá náà dáhùun: "N kò lè læ sí æjà-- emi jê ÷ranko pàtàkì n'ibi. Kò dára kí N ná æjà pèlú àwæn ÷ranko kékeré." Lêyìn náà, Ajá tún læ sùn.

Agbégbö kò mö ohun tí ó dé tí Ajá kò lè læ, «ùgbôn kò bínú. Ó læ sí æjà fúnraara rë, ó ná æjà ó sì padà silé rë pëlú àpò kan ti àlikàmà lêyìn wàkátì mêta. Ó rê ÷ díë, «ùgbön kò sinmi nítorí pé ó ní láti «e ìyëfun nibi ælæ. Nítorí èyí, ó læ silé ¿lêdë. Ó «'àlàyé ohun tí ó fê «e , ó sì «'àpèjuwé ohun tí ó dé ó fê gbà iranlôwô rë. »ùgbôn, bí i Ajá, ¿lêdë sæ pé kò lè «i«ê n'ibi ælæ nítorí pé ó jê ÷ranko pàtàkì ni oko. Ó sì sæ pé kò lè jê àimô-- nígbà tí ó padà sí pêtepête rè.

Lêyìn náà, Agbégbö kúrò nibë. Nígbà tí ó bá læ sí ödö ælæ fúnraara rë, ó mö pé ó níláti «i«ê púpö sì, «ùgbôn kò bínú rárá. Fún nõkan bí i wàkátì mejì, ó «e ìyëfun ní önà jêjê.

Nígbà tí ó fi ælæ tán, oòrù mú púpö, «ùgbön Agbégbô yìí kò sinmi nítorí pé ó gbôdö bërë sí se oúnj÷ fún ÷bí rë láìpê. Síbësíbë, kí ó tó bërë láti rò àwæn nõkan èèlò búrêdì jæ, ó læ s'ibi Ewúr÷ nítorí pé nínú àwæn ÷ranko ni oko, ó ní agbára júlæ. Nítorí náà, Agbégbö gbìyànjú láti gbà iranlôwô rë, «ùgbón kò «e orí ire. Ewúr÷-- bí i Ajá àti ¿lêdë têlë-- sæ pé pàtàkì pújæ láti «i«ê báyìí.

Agbégbö pinnu pé kò ní àkókó láti bínú sí alaigbônràn yìí-- nítorí náà ó «a öpölæpö igi jö láti tinábö. Ó «i«ê púpö láti se oúnj÷ fún ÷bí rë, oúnj÷ alê sì dára gan an. Inú àwæn æmædé rë dùn nígbà tí wôn gborùn oúnj÷. Gbogbo ÷ranko mìíràn mö pé Agbégbö pupa kékeré lè se oúnj÷ dáadáa, wôn sì náà gborùn búrêdì. »ùgbôn, aládùúgbò mêta-- Ewúr÷, Ajá àti ¿lêdë-- wá sílé Agbégbö láti gbà búrêdì díë fún ara wôn.

¿bí Agbégbö «ë«ë jókòó láti j÷un alê nígbà tí wæn dé. Lêyìn tí wôn bí Agbégbö léère pé bí wôn bá lè ní búrêdì díë, ó dáhùn, "¿yin mêtëëta kò ran mi lôwô pëlú i«ê tí ó ní láti fún búrêdì sise, «ùgbôn ÷ rò pé ÷ lè j÷ oúnj÷ tí mo se fún ÷bí mi fúnraara mi? Idáhùn mi ni ó tì! ¿ má bínú, «ùgbôn mo ní búrêdì to fún àwæn æmæ mi nìkan. Pëlúpëlú, ó dá mi l'ójú pé ÷ lè rí oúnj÷ dáadáa nibomíràn-- nítorí pé gbogbo yin jê ÷ranko pàtàkì gan an ni."

Lêyìn náà, ÷bí Agbégbö gbádùn oúnj÷ alê wæn. Ewúr÷, Ajá, àti ¿lêdë kò rí oúnj÷ dáadáa, nítorí náa wôn gbôdö læ sùn láì sí oúnj÷ rárá.

(Back)


Why Yoruba? ¬ Your Prof ¬ Syllabi ¬ Materials ¬ Student work ¬ Gallery ¬ Links
UW-Madison home ¬ African Languages home ¬ Email

Copyright © 2000 The Board of Regents of the University of Wisconsin System